وَإِنَّكَ لَعَلَىٰ خُلُقٍ عَظِيمٖ ٤
Wa innaka la'alā khuluqin 'azīm
Dájúdájú ìwọ sì wà lórí ìwà ńlá (ìwà alápọ̀n-ọ́nlé).
Ìtumọ̀: Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael
وَإِنَّكَ لَعَلَىٰ خُلُقٍ عَظِيمٖ ٤
Wa innaka la'alā khuluqin 'azīm
Dájúdájú ìwọ sì wà lórí ìwà ńlá (ìwà alápọ̀n-ọ́nlé).
Kíkà ní lẹ́tà Látìn jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún kíkà tí Qabas kọ láti inú èdè Lárúbáwá. Kọ́ àwọn lẹ́tà Lárúbáwá àti tajwīd fún ìpè tó péye.
Wa innaka la'ala khuluqin 'azim wà nínú Suratu Al-Qalam, 68:4.