Suratu Al-Qadr, aaya 1

97:1

إِنَّآ أَنزَلۡنَٰهُ فِي لَيۡلَةِ ٱلۡقَدۡرِ ١

Innā anzalnāhu fī laylatil-qadr

Dájúdájú Àwa sọ al-Ƙur’ān kalẹ̀ nínú Òru Abiyì.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah al-’Isrọ̄’; 17:106.