Wa la taqrabuz-zina

Ìtumọ̀: Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael

وَلَا تَقۡرَبُواْ ٱلزِّنَىٰٓۖ إِنَّهُۥ كَانَ فَٰحِشَةٗ وَسَآءَ سَبِيلٗا ٣٢

Walā taqrabuz-zinā innahū kāna fāhishatan wasā'a sabīlā

Ẹ má ṣe súnmọ́ àgbèrè. Dájúdájú ó jẹ́ ìwà burúkú. Ó sì burú ní ojú ọ̀nà.

Kíkà ní lẹ́tà Látìn jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún kíkà tí Qabas kọ láti inú èdè Lárúbáwá. Kọ́ àwọn lẹ́tà Lárúbáwá àti tajwīd fún ìpè tó péye.

Ka gbogbo Suratu Al-Isra

Àwọn ìbéèrè

Níbo ni Wa la taqrabuz-zina wà nínú Al-Kurani?

Wa la taqrabuz-zina wà nínú Suratu Al-Isra, 17:32.