Ud'uni astajib lakum

Ìtumọ̀: Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael

وَقَالَ رَبُّكُمُ ٱدۡعُونِيٓ أَسۡتَجِبۡ لَكُمۡۚ إِنَّ ٱلَّذِينَ يَسۡتَكۡبِرُونَ عَنۡ عِبَادَتِي سَيَدۡخُلُونَ جَهَنَّمَ دَاخِرِينَ ٦٠

Waqāla rabbukumud'ūnī astajib lakum innal-ladhīna yastakbirūna 'an 'ibādatī sayadkhulūna jahannama dākhirīn

Olúwa yín sọ pé: “Ẹ pè Mí, kí N̄g jẹ́pè yín. Dájúdájú àwọn tó ń ṣègbéraga nípa jíjọ́sìn fún Mi,1 wọn yóò wọ inú iná Jahanamọ ní ẹni yẹpẹrẹ.”

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ẹ wo sūrah Yūnus; 10:22 àti ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ rẹ̀.

Kíkà ní lẹ́tà Látìn jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún kíkà tí Qabas kọ láti inú èdè Lárúbáwá. Kọ́ àwọn lẹ́tà Lárúbáwá àti tajwīd fún ìpè tó péye.

Ka gbogbo Suratu Ghafir

Àwọn ìbéèrè

Níbo ni Ud'uni astajib lakum wà nínú Al-Kurani?

Ud'uni astajib lakum wà nínú Suratu Ghafir, 40:60.