Rabbana atina fid-dunya hasanah

Ìtumọ̀: Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael

وَمِنۡهُم مَّن يَقُولُ رَبَّنَآ ءَاتِنَا فِي ٱلدُّنۡيَا حَسَنَةٗ وَفِي ٱلۡأٓخِرَةِ حَسَنَةٗ وَقِنَا عَذَابَ ٱلنَّارِ ٢٠١

Waminhum man yaqūlu rabbanā ātinā fid-dunyā hasanatan wafil-ākhirati hasanatan waqinā 'adhāban-nār

Ó sì ń bẹ nínú wọn, ẹni tó ń sọ pé: “Olúwa wa, fún wa ní oore ní ayé àti oore ní ọ̀run, kí O sì ṣọ́ wa níbi ìyà Iná.”

Kíkà ní lẹ́tà Látìn jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún kíkà tí Qabas kọ láti inú èdè Lárúbáwá. Kọ́ àwọn lẹ́tà Lárúbáwá àti tajwīd fún ìpè tó péye.

Ka gbogbo Suratu Al-Baqarah

Àwọn ìbéèrè

Níbo ni Rabbana atina fid-dunya hasanah wà nínú Al-Kurani?

Rabbana atina fid-dunya hasanah wà nínú Suratu Al-Baqarah, 2:201.