Rabbighfir warham

Ìtumọ̀: Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael

وَقُل رَّبِّ ٱغۡفِرۡ وَٱرۡحَمۡ وَأَنتَ خَيۡرُ ٱلرَّٰحِمِينَ ١١٨

Waqur rabbighfir warham wa anta khayrur-rāhimīn

Sọ pé: “Olúwa mi, ṣàforíjìn, kí O sì kẹ́ (mi). Ìwọ sì l’óore jùlọ nínú àwọn aláàánú.”1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ āyah 14.

Kíkà ní lẹ́tà Látìn jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún kíkà tí Qabas kọ láti inú èdè Lárúbáwá. Kọ́ àwọn lẹ́tà Lárúbáwá àti tajwīd fún ìpè tó péye.

Ka gbogbo Suratu Al-Mu'minun

Àwọn ìbéèrè

Níbo ni Rabbighfir warham wà nínú Al-Kurani?

Rabbighfir warham wà nínú Suratu Al-Mu'minun, 23:118.