وَقَدۡ خَلَقَكُمۡ أَطۡوَارًا ١٤
Waqad khalaqakum atwārā
Ó sì kúkú ṣẹ̀dá yín láti ìrísí kan sí òmíràn (nínú oyún).1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ìyẹn ni pé, láti ìrísí àtọ̀ sí ìrísí ẹ̀jẹ̀ dídì, lẹ́yìn náà sí bááṣí ẹran.