Suratu Hud, aaya 95

11:95

كَأَن لَّمۡ يَغۡنَوۡاْ فِيهَآۗ أَلَا بُعۡدٗا لِّمَدۡيَنَ كَمَا بَعِدَتۡ ثَمُودُ ٩٥

Ka al lam yaghnaw fīhā alā bu'dal limadyana kamā ba'idat thamūd

Àfi bí ẹni pé wọn kò gbénú ìlú náà rí.1. Gbọ́, kí ìjìnnà sí ìkẹ́ máa jẹ́ ti ìran Mọdyan gẹ́gẹ́ bí ìran Thamūd ṣe jìnnà sí ìkẹ́.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìyẹn ni pé, wọ́n ṣẹ̀mí fún ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ọdún pẹ̀lú ayé gbẹdẹmukẹ, àmọ́ wọ́n parẹ́ láààrin ìṣẹ́jú kan.