Suratu At-Tawbah, aaya 106

9:106

وَءَاخَرُونَ مُرۡجَوۡنَ لِأَمۡرِ ٱللَّهِ إِمَّا يُعَذِّبُهُمۡ وَإِمَّا يَتُوبُ عَلَيۡهِمۡۗ وَٱللَّهُ عَلِيمٌ حَكِيمٞ ١٠٦

Wa ākharūna murjawna li amrillāhi immā yu'addhibuhum wa immā yatūbu 'alayhim wallāhu 'alīmun hakīm

Wọ́n so ọ̀rọ̀ àwọn yòókù rọ̀ ná títí àṣẹ Allāhu máa fi dé; yálà kí Ó jẹ wọ́n níyà tàbí kí Ó gba ìronúpìwàdà wọn.1 Allāhu sì ni Onímọ̀, Ọlọ́gbọ́n. 2

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìyẹn, àwọn tó ṣàì lọ sógun, àmọ́ tí wọn kò mú àwáwí irọ́ wá. [2] Àṣẹ náà dé nínú āyah 118 níwájú.