إِنَّهُۥ لَقَوۡلُ رَسُولٖ كَرِيمٖ ١٩
Innahū laqawlu rasūlin karīm
Dájúdájú (al-Ƙur’ān) ni ọ̀rọ̀ (tí A fi rán Jibrīl) Òjíṣẹ́, alápọ̀n-ọ́nlé,1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah al-Hāƙƙọh; 69:40.