إِلَّا عَجُوزٗا فِي ٱلۡغَٰبِرِينَ ١٧١
Illā 'ajūzan fil-ghābirīn
Àfi arúgbóbìnrin kan tí ó wà nínú àwọn tó ṣẹ́ kù lẹ́yìn (láààrin àwọn tí A parẹ́).1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Arúgbóbìnrin yẹn ni ìyàwó Ànábì Lūt – kí ọlà Allāhu máa bá a -.