37:2 فَٱلزَّٰجِرَٰتِ زَجۡرٗا ٢ Faz-zājirāti zajrā Allāhu tún fi àwọn mọlāika tó ń wọ́ ẹ̀ṣújò kiri tààrà bura.