Suratu An-Nisa, aaya 28

4:28

يُرِيدُ ٱللَّهُ أَن يُخَفِّفَ عَنكُمۡۚ وَخُلِقَ ٱلۡإِنسَٰنُ ضَعِيفٗا ٢٨

Yurīdullāhu an yukhaffifa 'ankum wakhuliqal-insānu da'īfā

Allāhu fẹ́ gbé e fúyẹ́ fún yín; A sì ṣẹ̀dá ènìyàn ní ọ̀lẹ.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìyẹn ni pé, àdámọ́ lílẹ wà nínú ìṣẹ̀dá ènìyàn.