بَل رَّفَعَهُ ٱللَّهُ إِلَيۡهِۚ وَكَانَ ٱللَّهُ عَزِيزًا حَكِيمٗا ١٥٨
Bar rafa'ahullāhu ilayhi wakānallāhu 'azīzan hakīmā
bí kò ṣe pé Allāhu gbé e wá sókè lọ́dọ̀ Rẹ̀ ni. Allāhu sì ń jẹ́ Alágbára, Ọlọ́gbọ́n.1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Āyah yìí kò túmọ̀ sí "ṣùgbọ́n A gbé e ga ní ipò" gẹ́gẹ́ bí àwọn kan ṣe lérò.