وَلَقَدۡ جَآءَهُم مِّنَ ٱلۡأَنۢبَآءِ مَا فِيهِ مُزۡدَجَرٌ ٤
Walaqad jā'ahum minal-ambā'i mā fīhi muzdajar
Dájúdájú wáàsí tí ó ń kọ aburú1 wà nínú àwọn ìró tó dé bá wọn.
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 “Muzdajar” wáàsí tó le tó kún fún ìṣẹ̀rùbà àti àpẹ̀ẹrẹ ìjìyà tó ṣẹlẹ̀ sí àwọn ẹni àkọ́kọ́ nínú àwọn ọ̀tá òdodo.