Suratu Al-Ma'un, aaya 4

107:4

فَوَيۡلٞ لِّلۡمُصَلِّينَ ٤

Fawaylul lil-musallīn

Ègbé ni fún àwọn (mùnááfìkí) tó ń kírun;1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Pẹ̀lú ìrun wákàtí márààrún lójoojúmọ́ ní àsìkò rẹ̀, ó ti run gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wẹẹrẹ dànù. Ìrònúpìwàdà àti ìtọrọ-àforíjìn l’ó máa run àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńláńlá dànù.