۞ مَّآ أَشۡهَدتُّهُمۡ خَلۡقَ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ وَلَا خَلۡقَ أَنفُسِهِمۡ وَمَا كُنتُ مُتَّخِذَ ٱلۡمُضِلِّينَ عَضُدٗا ٥١
Mmā ashhattuhum khalqas-samāwāti wal-ardi walā khalqa anfusihim wamā kuntu muttakhidhal-mudillīna 'adudā
Èmi kò fi wọ́n ṣe ẹlẹ́rìí sí ìṣẹ̀dá àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀, àti ìṣẹ̀dá àwọn gan-an alára. Èmi kò sì mú àwọn aṣinilọ́nà ní olùrànlọ́wọ́.1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ó ṣe wá jẹ́ tí ẹ̀ ń sọ wọ́n di akẹgbẹ́ Mi?