Suratu Al-Baqarah, aaya 152

2:152

فَٱذۡكُرُونِيٓ أَذۡكُرۡكُمۡ وَٱشۡكُرُواْ لِي وَلَا تَكۡفُرُونِ ١٥٢

Fadhkurūnī adhkurkum washkurū lī walā takfurūn

nítorí náà, ẹ rántí Mi, Kí N̄g rántí yín.1 Ẹ dúpẹ́ fún Mi, ẹ má ṣàì moore sí Mi.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 “Ìrántí Allāhu” láti ọ̀dọ̀ ẹ̀dá sí Ẹlẹ́dàá ni àwọn iṣẹ́ ìjọ́sìn. Àmọ́ “Ìrántí Allāhu” láti ọ̀dọ̀ Allāhu Ẹlẹ́dàá sí ẹ̀dá ni àwọn ẹ̀san iṣẹ́ ìjósìn.