Fadhkuruni adhkurkum

Ìtumọ̀: Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael

فَٱذۡكُرُونِيٓ أَذۡكُرۡكُمۡ وَٱشۡكُرُواْ لِي وَلَا تَكۡفُرُونِ ١٥٢

Fadhkurūnī adhkurkum washkurū lī walā takfurūn

nítorí náà, ẹ rántí Mi, Kí N̄g rántí yín.1 Ẹ dúpẹ́ fún Mi, ẹ má ṣàì moore sí Mi.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 “Ìrántí Allāhu” láti ọ̀dọ̀ ẹ̀dá sí Ẹlẹ́dàá ni àwọn iṣẹ́ ìjọ́sìn. Àmọ́ “Ìrántí Allāhu” láti ọ̀dọ̀ Allāhu Ẹlẹ́dàá sí ẹ̀dá ni àwọn ẹ̀san iṣẹ́ ìjósìn.

Kíkà ní lẹ́tà Látìn jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún kíkà tí Qabas kọ láti inú èdè Lárúbáwá. Kọ́ àwọn lẹ́tà Lárúbáwá àti tajwīd fún ìpè tó péye.

Ka gbogbo Suratu Al-Baqarah

Àwọn ìbéèrè

Níbo ni Fadhkuruni adhkurkum wà nínú Al-Kurani?

Fadhkuruni adhkurkum wà nínú Suratu Al-Baqarah, 2:152.