لَا يَسۡتَطِيعُونَ نَصۡرَهُمۡ وَهُمۡ لَهُمۡ جُندٞ مُّحۡضَرُونَ ٧٥
Lā yastatī'ūna nasrahum wahum lahum jundum muhdarūn
Wọn kò sì lè ṣe àrànṣe fún wọn; ṣebí àwọn òrìṣà ni ọmọ ogun tí (àwọn mọlāika) máa kó wá sínú Iná fún àwọn abọ̀rìṣà (láti fi jẹ wọ́n níyà).1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ẹ wo sūrah Mọryam; 19:82 àti sūrah al-’Anbiyā’; 21:98.