Suratu Ghafir, aaya 19

40:19

يَعۡلَمُ خَآئِنَةَ ٱلۡأَعۡيُنِ وَمَا تُخۡفِي ٱلصُّدُورُ ١٩

Ya'lamu khā'inatal-a'yuni wamā tukhfis-sudūr

(Allāhu) mọ ojú ìjàǹbá àti ohun tí àwọn ọkàn fi pamọ́.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ojú ìjàǹbá ni ojú tó ń yọ́ obìnrin wò ní ọ̀nà àìtọ́ àti àwọn ìwòkíwò mìíràn.