وَقَالُواْ ٱلۡحَمۡدُ لِلَّهِ ٱلَّذِيٓ أَذۡهَبَ عَنَّا ٱلۡحَزَنَۖ إِنَّ رَبَّنَا لَغَفُورٞ شَكُورٌ ٣٤
Waqālul-hamdu lillāhil-ladhī adhhaba 'annal-hazana inna rabbanā laghafūrun shakūr
Wọ́n yóò sọ pé: “Gbogbo ẹyìn ń jẹ́ ti Allāhu, Ẹni tí Ó mú ìbànújẹ́ kúrò fún wa. Dájúdájú Olúwa wa ni Aláforíjìn, Ọlọ́pẹ́,1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Nínú orúkọ àti ìròyìn Allāhu ni “Ṣākir” àti “Ṣakūr”.