Suratu As-Sajdah, aaya 20

32:20

وَأَمَّا ٱلَّذِينَ فَسَقُواْ فَمَأۡوَىٰهُمُ ٱلنَّارُۖ كُلَّمَآ أَرَادُوٓاْ أَن يَخۡرُجُواْ مِنۡهَآ أُعِيدُواْ فِيهَا وَقِيلَ لَهُمۡ ذُوقُواْ عَذَابَ ٱلنَّارِ ٱلَّذِي كُنتُم بِهِۦ تُكَذِّبُونَ ٢٠

Wa ammal-ladhīna fasaqū fama'wāhumun-nāru kullamā arādū an yakhrujū minhā u'īdū fīhā waqīla lahum dhūqū 'adhāban-nāril-ladhī kuntum bihī tukaddhibūn

Ní ti àwọn tó balẹ̀jẹ́, Iná ni ibùgbé wọn. Ìgbàkígbà tí wọ́n bá fẹ́ jáde kúrò nínú rẹ̀, A ó sì máa dá wọn padà sínú rẹ̀. A sì máa sọ fún wọn pé: “Ẹ tọ́ ìyà Iná tí ẹ̀ ń pè ní irọ́ wò.”1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Āyah yìí dúró sórí àwọn kèfèrí àti munāfiki, kì í ṣe mùsùlùmí ẹlẹ́ṣẹ̀ tí ó kọ́kọ́ wọ inú Iná ṣíwájú kí ó tó wọ inú Ọgbà Ìdẹ̀ra.