إِلَّا طَرِيقَ جَهَنَّمَ خَٰلِدِينَ فِيهَآ أَبَدٗاۚ وَكَانَ ذَٰلِكَ عَلَى ٱللَّهِ يَسِيرٗا ١٦٩
Illā tarīqa jahannama khālidīna fīhā abadan wakāna dhālika 'alallāhi yasīrā
Àyàfi ojú-ọ̀nà iná Jahanamọ. Olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀ títí láéláé. Ìyẹn sì ń jẹ́ ìrọ̀rùn fún Allāhu.1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Èyí wà fún ẹni tí ó bá kú sínú àìgbàgbọ́ lẹ́yìn tí ìkéde ẹ̀sìn ’Islām ti dé etí ìgbọ́ rẹ̀. Bákan náà, ẹ wo āyah 48 àti āyah 116.