Suratu Al-Waqi'ah, aaya 40

56:40

وَثُلَّةٞ مِّنَ ٱلۡأٓخِرِينَ ٤٠

Wathullatum minal-ākhirīn

Wọ́n tún pọ̀ nínú àwọn ẹni Ìkẹ́yìn.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Àwọn ẹni àkọ́kọ́ dúró fún àwọn ènìyàn láti àsìkò Ànábì Ādam títí di àsìkò Ànábì ‘Īsā - kí ọlà Allāhu máa bá wọn -. Àwọn ẹni Ìkẹ́yìn sì dúró fún ìjọ Ànábì wa nìkan - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a -.