Suratu Al-Qamar, aaya 27

54:27

إِنَّا مُرۡسِلُواْ ٱلنَّاقَةِ فِتۡنَةٗ لَّهُمۡ فَٱرۡتَقِبۡهُمۡ وَٱصۡطَبِرۡ ٢٧

Innā mursilun-nāqati fitnatal lahum fartaqibhum wastabir

Dájúdájú Àwa máa rán abo ràkúnmí sí wọn; (ó máa jẹ́) àdánwò fún wọn. Nítorí náà, máa wò wọ́n níran ná, kí o sì ṣe sùúrù.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ṣe sùúrù láì níí fi ẹjọ́ wọn sùn mọ́.