عُتُلِّۭ بَعۡدَ ذَٰلِكَ زَنِيمٍ ١٣
'Utulli ba'da dhālika zanīm
ọ̀dájú. Lẹ́yìn ìyẹn, ògbólógbòó ẹni ibi (àsáwọ̀1, ọmọ zina) ni.
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ìyẹn ni pé, kì í ṣe ojúlówó ọmọ ìran Ƙuraeṣ; àsọdọmọ ni. Ẹni náà ni Walīd ọmọ Mugīrah, ẹni tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìdínlógún nígbà tí Mugīrah sọ ọ́ di ọmọ rẹ̀.