Suratu Al-Mumtahanah, aaya 5

60:5

رَبَّنَا لَا تَجۡعَلۡنَا فِتۡنَةٗ لِّلَّذِينَ كَفَرُواْ وَٱغۡفِرۡ لَنَا رَبَّنَآۖ إِنَّكَ أَنتَ ٱلۡعَزِيزُ ٱلۡحَكِيمُ ٥

Rabbanā lā taj'alnā fitnatal lilladhīna kafarū waghfir lanā rabbanā innaka antal-'azīzul-hakīm

Olúwa wa, má ṣe wá ní àdánwò fún àwọn tó ṣàì gbàgbọ́.1 Foríjìn wá, Olúwa wa. Dájúdájú Ìwọ ni Alágbára, Ọlọ́gbọ́n.”

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìyẹn ni pé, má fi àwọn kèfèrí borí wa, kí ayé má fi lérò pé wọ́n wà lórí òdodo ni wọ́n fi borí wa.