Suratu Al-Ma'idah, aaya 90

5:90

يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُوٓاْ إِنَّمَا ٱلۡخَمۡرُ وَٱلۡمَيۡسِرُ وَٱلۡأَنصَابُ وَٱلۡأَزۡلَٰمُ رِجۡسٞ مِّنۡ عَمَلِ ٱلشَّيۡطَٰنِ فَٱجۡتَنِبُوهُ لَعَلَّكُمۡ تُفۡلِحُونَ ٩٠

Yā'ayyuhal-ladhīna āmanū innamal-khamru wal-maysiru wal-ansābu wal-azlāmu rijsum min 'amalish-shaytāni fajtanibūhu la'allakum tuflihūn

Ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, dájúdájú ọtí,1 tẹ́tẹ́, àwọn òrìṣà àti iṣẹ́ yíyẹ̀wò2, ẹ̀gbin nínú iṣẹ́ aṣ-Ṣaetọ̄n ni. Nítorí náà, ẹ jìnnà sí i nítorí kí ẹ lè jèrè.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah al-Baƙọrah; 2:219. [2] Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ āyah 3.