وَمَا خَلَقَ ٱلذَّكَرَ وَٱلۡأُنثَىٰٓ ٣
Wamā khalaqadh-dhakara wal-unthā
Ó tún fi Ẹni tí Ó dá akọ àti abo búra.1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Allāhu Ẹlẹ́dàá ni Ẹni tí Ó dá akọ àti abo. Ó sì ń fi ara Rẹ̀ búra.
وَمَا خَلَقَ ٱلذَّكَرَ وَٱلۡأُنثَىٰٓ ٣
Wamā khalaqadh-dhakara wal-unthā
Ó tún fi Ẹni tí Ó dá akọ àti abo búra.1
1 Allāhu Ẹlẹ́dàá ni Ẹni tí Ó dá akọ àti abo. Ó sì ń fi ara Rẹ̀ búra.