Suratu Al-Hijr, aaya 91

15:91

ٱلَّذِينَ جَعَلُواْ ٱلۡقُرۡءَانَ عِضِينَ ٩١

Alladhīna ja'alul-qur'āna 'idīn

àwọn tí wọ́n sọ al-Ƙur’ān di ìpínkúpìn-ín,1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ẹ wo bí àwọn aláìgbàgbọ́ ṣe pín al-Ƙur’ān sí ìpínkúpìn-ín nínú sūrah al-’Anbiyā’; 21:3-5.