Suratu Al-Hijr, aaya 78

15:78

وَإِن كَانَ أَصۡحَٰبُ ٱلۡأَيۡكَةِ لَظَٰلِمِينَ ٧٨

Wa in kāna ashābul-aykati lazālimīn

Àwọn ará ’Aekah1 náà jẹ́ alábòsí.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 ’Aekah tún túmọ̀ sí igbó. Ìyẹn ni pé, ìlú tí ó wà nínú igbó. Ará ’Aekah ni ìjọ Ànábì Ṣu‘aeb - kí ọlà Allāhu máa bá a -.