Suratu Al-Baqarah, aaya 10

2:10

فِي قُلُوبِهِم مَّرَضٞ فَزَادَهُمُ ٱللَّهُ مَرَضٗاۖ وَلَهُمۡ عَذَابٌ أَلِيمُۢ بِمَا كَانُواْ يَكۡذِبُونَ ١٠

Fī qulūbihim maradun fazādahumullāhu maradan walahum 'adhābun alīmu bimā kānū yakdhibūn

Àrùn kan wà nínú ọkàn wọn1, nítorí náà Allāhu ṣe àlékún àrùn (náà) fún wọn. Ìyà ẹlẹ́ta-eléro sì wà fún wọn nítorí pé wọ́n ń parọ́.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Àrùn iyèméjì àti ìṣojúméjì sí āyah al-Ƙur’ān.