وَٱتۡلُ عَلَيۡهِمۡ نَبَأَ ٱلَّذِيٓ ءَاتَيۡنَٰهُ ءَايَٰتِنَا فَٱنسَلَخَ مِنۡهَا فَأَتۡبَعَهُ ٱلشَّيۡطَٰنُ فَكَانَ مِنَ ٱلۡغَاوِينَ ١٧٥
Watlu 'alayhim naba'al-ladhī ātaynāhu āyātinā fansalakha minhā fa atba'ahush-shaytānu fakāna minal-ghāwīn
Ka ìròyìn ẹni tí A fún ní àwọn āyah Wa fún wọn, tí ó yọra rẹ̀ sílẹ̀ níbi àwọn āyah náà.1 Nítorí náà, aṣ-Ṣaetọ̄n tẹ̀lé e lẹ́yìn. Ó sì wà nínú àwọn olùṣìnà.
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ó pa ìmọ̀ tì bí ìgbà tí ejò bá bọ́ ìhọ rẹ̀ sílẹ̀.