Suratu Al-A'raf, aaya 111

7:111

قَالُوٓاْ أَرۡجِهۡ وَأَخَاهُ وَأَرۡسِلۡ فِي ٱلۡمَدَآئِنِ حَٰشِرِينَ ١١١

Qālū arjih wa akhāhu wa arsil fil-madā'ini hāshirīn

Wọ́n sì wí pé: “Fún òun àti arákùnrin rẹ̀ lọ́jọ́,1 kí o sì rán àwọn akónijọ2 sí àwọn ìlú,

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ọjọ́ ìpàdé náà ni ó jẹyọ nínú sūrah Tọ̄hā; 20:59. [2] Àwọn ni àwọn ọlọ́pàá Fir‘aon.