Suratu Yunus, aaya 47

10:47

وَلِكُلِّ أُمَّةٖ رَّسُولٞۖ فَإِذَا جَآءَ رَسُولُهُمۡ قُضِيَ بَيۡنَهُم بِٱلۡقِسۡطِ وَهُمۡ لَا يُظۡلَمُونَ ٤٧

Walikulli ummatir rasūlun fa idhā jā'a rasūluhum qudiya baynahum bil-qisti wahum lā yuzlamūn

Òjíṣẹ́ ti wà fún ìjọ kọ̀ọ̀kan.1 Nítorí náà, nígbà tí Òjíṣẹ́ wọn bá dé, A óò ṣèdájọ́ láààrin wọn pẹ̀lú déédé; A ò sì níí ṣàbòsí sí wọn.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìyẹn àwọn ìjọ tí Allāhu rán Òjíṣẹ́ sí torí pé, kì í ṣe gbogbo ìran tàbí ẹ̀yà ló ní òjíṣẹ́.