أَلۡقِيَا فِي جَهَنَّمَ كُلَّ كَفَّارٍ عَنِيدٖ ٢٤
Alqiyā fī jahannama kulla kaffārin 'anīd
Ẹ̀yin mọlāika méjèèjì,1 ẹ ju gbogbo aláìgbàgbọ́ olóríkunkun sínú iná Jahanamọ.
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ìyẹn, olùdarí kan àti ẹlẹ́rìí kan nínú àwọn mọlāika.