Suratu Luqman, aaya 2

31:2

تِلۡكَ ءَايَٰتُ ٱلۡكِتَٰبِ ٱلۡحَكِيمِ ٢

Tilka āyātul-kitābil-hakīm

Ìwọ̀nyí ni àwọn āyah Tírà tí ó kún fún ọgbọ́n.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Pípe al-Ƙur’ān ní “hakīm” túmọ̀ sí tírà tí ó kún fún ọgbọ́n, tírà tí ó ń ṣe ìdájọ́ àti tírà tí wọ́n to àwọn āyah rẹ̀ àti sūrah rẹ̀ tó gún régé láì sí ìdàrúdàpọ̀ àti ìtakora kan nínú rẹ̀.