Suratu Fatir, aaya 17

35:17

وَمَا ذَٰلِكَ عَلَى ٱللَّهِ بِعَزِيزٖ ١٧

Wamā dhālika 'alallāhi bi'azīz

Ìyẹn kò sì ṣòroo ṣe fún Allāhu.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Kò kó wàhálà kan kan bá Allāhu Ẹlẹ́dàá.