فَمَا ظَنُّكُم بِرَبِّ ٱلۡعَٰلَمِينَ ٨٧
Famā zannukum birabbil-'ālamīn
Kí sì ni èrò ọkàn yín sí Olúwa gbogbo ẹ̀dá?”1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ìyẹn ni pé, ẹ̀san rere ni ẹ̀ ń retí ni tàbí ẹ̀san aburú?
فَمَا ظَنُّكُم بِرَبِّ ٱلۡعَٰلَمِينَ ٨٧
Famā zannukum birabbil-'ālamīn
Kí sì ni èrò ọkàn yín sí Olúwa gbogbo ẹ̀dá?”1
1 Ìyẹn ni pé, ẹ̀san rere ni ẹ̀ ń retí ni tàbí ẹ̀san aburú?