Suratu As-Saffat, aaya 103

37:103

فَلَمَّآ أَسۡلَمَا وَتَلَّهُۥ لِلۡجَبِينِ ١٠٣

Falammā aslamā watallahū lil-jabīn

Nígbà tí àwọn méjèèjì juwọ́ jusẹ̀ sílẹ̀, tí (Ànábì ’Ibrọ̄hīm) sì dojú1 (ọmọ) rẹ̀ bolẹ̀,

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìtúmọ̀ “jẹbīn” ni iwájú orí.