Suratu Ar-Rum, aaya 3

30:3

فِيٓ أَدۡنَى ٱلۡأَرۡضِ وَهُم مِّنۢ بَعۡدِ غَلَبِهِمۡ سَيَغۡلِبُونَ ٣

Fī adnal-ardi wahum mim ba'di ghalabihim sayaghlibūn

ní àwọn ilẹ̀ tó wà nítòsí (erékùsù Lárúbáwá).1 Lẹ́yìn ìṣẹ́gun wọn, àwọn náà máa ṣẹ́gun wọn

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìyẹn ní ilẹ̀ Siria, ‘Irāƙ, Jọdan àti Palẹstin.