ٱلَّذِينَ إِذَا ٱكۡتَالُواْ عَلَى ٱلنَّاسِ يَسۡتَوۡفُونَ ٢
Alladhīna idhaktālū 'alan-nāsi yastawfūn
àwọn (òǹtajà) tó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n bá wọn n̄ǹkan lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn,1 wọ́n á gbà á ní ẹ̀kún,
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 “Àwọn ènìyàn” ní àyè yìí dúró fún bíi “ àwọn olóko”.