Suratu Al-Mu'minun, aaya 4

23:4

وَٱلَّذِينَ هُمۡ لِلزَّكَوٰةِ فَٰعِلُونَ ٤

Walladhīna hum liz-zakawāti fā'ilūn

àti àwọn tó ń ṣe àfọ̀mọ́ (ẹ̀mí àti ara) wọn.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Ìtúmọ̀ mìíràn fún āyah yìí nìyí: “àti àwọn tó ń yọ zakāh”.