Suratu Al-Isra, aaya 88

17:88

قُل لَّئِنِ ٱجۡتَمَعَتِ ٱلۡإِنسُ وَٱلۡجِنُّ عَلَىٰٓ أَن يَأۡتُواْ بِمِثۡلِ هَٰذَا ٱلۡقُرۡءَانِ لَا يَأۡتُونَ بِمِثۡلِهِۦ وَلَوۡ كَانَ بَعۡضُهُمۡ لِبَعۡضٖ ظَهِيرٗا ٨٨

Qul la inijtama'atil-insu wal-jinnu 'alā an ya'tū bimithli hādhal-qur'āni lā ya'tūna bimithlihī walaw kāna ba'duhum liba'din zahīrā

Sọ pé: “Dájúdájú tí àwọn ènìyàn àti àlùjànnú bá parapọ̀ láti mú irú al-Ƙur’ān yìí wá, wọn kò lè mú irú rẹ̀ wá, apá kan wọn ìbáà jẹ́ olùrànlọ́wọ́ fún apá kan.”1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Bí wọ́n bá gbìyànjú rẹ̀, wọ́n máa fìdí rẹmi.