Suratu Al-Isra, aaya 16

17:16

وَإِذَآ أَرَدۡنَآ أَن نُّهۡلِكَ قَرۡيَةً أَمَرۡنَا مُتۡرَفِيهَا فَفَسَقُواْ فِيهَا فَحَقَّ عَلَيۡهَا ٱلۡقَوۡلُ فَدَمَّرۡنَٰهَا تَدۡمِيرٗا ١٦

Wa idhā aradnā an nuhlika qaryatan amarnā mutrafīhā fafasaqū fīhā fahaqqa 'alayhal-qawlu fadammarnāhā tadmīrā

Nígbà tí A bá sì gbèrò láti pa ìlú kan run, A máa pa àwọn onígbẹdẹmukẹ ìlú náà láṣẹ (rere). Àmọ́ wọ́n máa ṣèbàjẹ́ sínú ìlú. Ọ̀rọ̀ náà yó sì kò lé wọn lórí. A ó sì pa wọ́n rẹ́ pátápátá.1

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Āyah yìí jọ sūrah al-’Ani‘ām; 6:123.