Suratu Al-Imran, aaya 74

3:74

يَخۡتَصُّ بِرَحۡمَتِهِۦ مَن يَشَآءُۗ وَٱللَّهُ ذُو ٱلۡفَضۡلِ ٱلۡعَظِيمِ ٧٤

Yakhtassu birahmatihī man yashā'u wallāhu dhul-fadlil-'azīm

(Allāhu) ń fi ìkẹ́ Rẹ̀1 ṣa ẹni tí Ó bá fẹ́ lẹ́ṣà. Allāhu ni Olóore ńlá.

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 “Rahmọh” ní àyè yìí dúró fún ipò Ànábí àti Òjíṣẹ́ tí Allāhu fi ṣa Ànábì wa - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu má abá a - lẹ́ṣà, àmọ́ ti ìlara kò jẹ́ kí àwon onítírà gbádùn.