Suratu Al-Imran, aaya 46

3:46

وَيُكَلِّمُ ٱلنَّاسَ فِي ٱلۡمَهۡدِ وَكَهۡلٗا وَمِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ ٤٦

Wayukallimun-nāsa fil-mahdi wakahlan waminas-sālihīn

Ó máa bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ lórí ìtẹ́ ní òpóǹló àti nígbà tó bá dàgbà.1 Ó sì wà nínú àwọn ẹni rere.”

Àlàyé ìsàlẹ̀

1 Gẹ́gẹ́ bí ọmọdé kan ní àsìkò Juraej àti ọmọdé kan mìíràn ṣe sọ̀rọ̀ lórí ìtẹ́ ní òpóǹló.”