إِنَّ ٱلَّذِينَ يُنَادُونَكَ مِن وَرَآءِ ٱلۡحُجُرَٰتِ أَكۡثَرُهُمۡ لَا يَعۡقِلُونَ ٤
Innal-ladhīna yunādūnaka min warā'il-hujurāti aktharuhum lā ya'qilūn
Dájúdájú àwọn tó ń pè ọ́ láti ẹ̀yìn àwọn yàrá1, ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò ṣe làákàyè.
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 “Àwọn yàrá” dúró fún “òdidi ilé”. Ìyẹn ni pé, àwọn tí wọ́n ń lọgun pé Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a - láti iwájú ilé rẹ̀ ní ìta.