فَذَكِّرۡ إِن نَّفَعَتِ ٱلذِّكۡرَىٰ ٩
Fadhakkir in nafa'atidh-dhikrā
Nítorí náà, ṣèrántí ní àyè tí ìrántí ti wúlò.1
Àlàyé ìsàlẹ̀
1 Ìyẹn ni pé, wọ́n fẹ́ kí ṣíṣe ìrántí ọ̀rọ̀ Allāhu jìnnà sí àyè ìhunrírà (bí ilé ọtí), ilé eré àti ilé àwàdà.